Namibia yoo san owo gba-ma binu to le ni ẹ̀gbẹ̀rúnlona-ọgọ́rùn ún dola($8,330; £5,798) owo orile ede naa fun awon ebi eniyan ti eranko bi I ooni ati erinmilokun pa.
Minisita fun ayika ati igbafe Pohamba Shifeta ti so pe:“Awon ko ni san owo gba-ma-binu ohun fun awon ti ooni ati erinmilokun pa nibi ti won ti n luwe tabi we ninu omi nitori pe, won mo ohun ti won le e se lati gba ara won sile nibi isele burku ohun.”
Iwe akosile orile ede Namibia so pe “Awon mesan an ni awon eranko buruku yii pa lodun 2016, ti mefa ku lodun 2017”.
Iroyin so pe awon eniyan merin lo ti pdadanu emi won . meta ni ooni pa, ti erinmilokun si pa enikan lodun yii.
Ogbeni Shifeta ti ro awon eniyan lati maa pon omi lo sile won fun wiwe tabi fo aso won , ki o le dekun ikolu burku yii.
No comments:
Post a Comment