Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Tuesday, September 19, 2017

Eto Alaafia ati Ilaja Bere Ni Ekun Kasai Lori Rogbodiyan To N Sele

Ipade fun eto alaafia ati ilaja ni orile ede Congo lekun Kasai yoo bere lojo Kerindinlogun ,Ojo Aje,  Osu kesan an .
Ipade olojo-meta naa,yoo waye ni Kananga nibi  ti rogbodiyan  gbe sele, ni eyi ti yoo ko awon adari elesin, oloselu ati awon ajo ti ki I se ti Ijoba  lati ekun marun un naa jo.
Wahala naa be sile lodun kan seyin nigba ti  awon omo-ologun Congo seku  pa adari  a-ji-ja-gbara  ti ekun  eya Kamwina Nsapu.
Lati igba naa , o ti le ni egberun  meta awon eniyan to ti padanu emi won , gege bi ijo Catholic se so.
Ajo agbaye  so pe, o le ni milionu kan awon eniyan to ti padanu ibugbe won,ti won tun  so  pe ti rogbodiyan naa ba tesiwaju , o daju pe, yoo mu ipalara pupo ba awon eniyan lagbegbe naa.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages