Nadal, eni ti o ti gba ife eye idije ohun nigba merindinlogun ati ainiye ami eye lorisirisi, gbegba oroke ninu ipo ate ohun nigbati akegbe re Roger Federer ti o orile-ede Switzerland si se ipo keji.
Omo bibi orile-ede Spain ohun, Rafael Nadal, se ipo kini ninu atejade ipo ate ATP ti awon okunrin ninu ere idaraya naa ti o jade lojo aje(Monday).
Nadal se ipo kini, Roger Federer se ipo keji, nigbati Andy Murray si se ipo keta.
Bakan naa, Alexander Zverev ti o orile-ede Germany gba ipo kerin, Marin Cilic sepo karun-un, Novak Djokovic si se ipo kefa.
Gege bi atejade ipo ate (ATP) ohun

- Rafael Nadal (Spain) ni ami 9,465
- Roger Federer (Switzerland) ni ami 7,505.
- Andy Murray (United Kingdom) ni ami 6,790.
- Alexander Zverev (Germany) ni ami 4,470.
- Marin Cilic (Croatia) ni ami 4,155.
- Novak Djokovic (Serbia) ni ami 4,125.
- Dominic Thiem (Austria) ni ami 4,030.
- Stan Wawrinka (Switzerland) ni ami 3,690.
- Grigor Dimitrov (Bulgaria) ami 3,575.
- Pablo Carreño Busta (Spain) 2,855.

No comments:
Post a Comment