Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Tuesday, November 14, 2017

Ethiopia Fopin si ifehonuhan



Ethiopia Fopin si ifehonuhan
Iroyin lati ile-ise radio ti Ijoba orile ede Ethopia so pe, ijoba orile-ede ohun ti kede lojo-eti (Friday)  lati fopin si ifehonuhan ati iwode jake-jado orile ede naa.
Awon alase so pe,   awon gbe igbese yii lati le je ki eto aabo tubo fese mule  lorile- ede naa.
Minisita fun eto aabo Siraj Fagessa, nigba to n ba awon akoroyin soro pe, ifenuko  yii waye nibi ipade ti igbimo alase to n ri si eto aabo se , ni lati  dekun  ifehonuhan ati iwode ti o le sokufa ifemi ati dukia sofo lorile ede naa.
Minisita tesiwaju pe,alaafia joba lorile ede Ethopia  nigba ti awon kede eto ilu o-fararo fun osu mewaa gbako, amo ni kete ti awon mu eto yii kuro ni awon  apa ibikan loril ede naa  bere si  tun n gbona jojo.
Orile ede Ehtopia je okan lara orile ede Afrika ti eto aabo re gbohunje fegbe- gbawo bo.ifehonuhan ti Oromo se lo da wahala sile lorile ede naa, ni eyi ti o faa ki won kede eto ilu o-fararo ni osu kewaa odun 2016.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages