Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Tuesday, November 14, 2017

Morocco fagba han orile-ede Ivory Coast lati pegede fun idije boolu agbaye


Morocco vs Ivory Coast
Orile-ede Morocco fagba han iko agbaboolu orile-ede Ivory Coast lojo aiku(Saturday), pelu ami ayo meji sodo(2-0), ninu ifesewonse keyin ipegede fun idije boolu agbaye to n bo lona lodun 2018 lorile-ede Russia.
Ami ayo mejeeji ohun waye lati owo Nabil Dirar ati Medhi Benatia, eleyi ti o mu ki orile-ede Morocco jawe olubori ti won si pegede fun idije naa, pelu ami mejila loke tente tabili.
Bio tile jepe, orile-ede Morocco nilo ami dogba-dogba ninu ifesewonse keyin ohun lati pegede fun idije naa, sugbon ti won  jawe olubori pelu ami ayo meji sodo.
Iroyin so pe, lati odun 1998 ni iko agbaboolu orile-ede Morocco ti kopa ninu irufe idije boolu agbaye yii, eyi ti o waye lorile-ede Faranse.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages