Ijamba ina gbemi eniyan metala ni agbegbe Ho Chi Minh lojo Eti(Friday) ni Vietnamese.
Gege bi ile-ise eka panapana se so, won ni isele ohun lagbara pupo ti awon eniyan metadinlogbon miran si farapa yanayana.
“Opolopo awon ti o ba isele naa lo ni eefin ina sekupa, beesini a tun ri awon miran ti o padanu emi won latari fifo oju ferese ile naa,”
“Awon ti o farapa ni itoju lo lowo lori won bayii, beesini a tun si n wa awon miran ti o ku sinu ile naa.”
Ijamba ina ohun bere laago kan owuro ojoRu(Thursday) ni isale ile naa ki o to gba gbogbo eka miran ninu ile ohun ka.
Orisirisi ohun igbalode pipana lati ko lo sibe lati dekun owo ina ohun.
No comments:
Post a Comment