
Iko agbaboolu Arsenal kopa daradara ninu ifesewonse ipele keta si asekagba idije Europa League, leyin ti fagbahan iko agbaboolu CSKA Moscow pelu ami-ayo merin sookan(4-1) ninu ifigagbaga akoko ifesewonse naa,
Bakan naa si ni, iko agbaboolu Atletico Madrid ko gbeyin, leyin ti iko ohun naa fagbahan Sporting Lisbon pelu ami-ayo meji sodo(2-0) lojoBo(Thursday).

Iko agbaboolu Lazio naa gbo ewuro soju Salzburg pelu ami-ayo merin si meji(4-2), beesin iko agbabolu RB Leipzig fagbahan Olympique de Marseille pelu ami-ayo kan sodo(1-0).
Koke gba ami-ayo kinni wole niseju perete ti ifesewonse ohun bere, kii Antoine Griezmann ko to fobale ki saa akoko o to wa si ipari.
No comments:
Post a Comment