Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Tuesday, April 24, 2018

Awon omo ogun se ikolu si ipago omo ogun olote boko haram



Iko omo ogun Naijiria ti se ikolu n la si ipago awon omo ogun olote Boko Haram lojo Aje(Monday), ti o wa lagbegbe Benisheikh, nipinle Borno.
Igbakeji adari eka igbohunsafefe fun ise akanse Operation Lafiya Dole, balogun Onyema Nwachukwu, lo so oro naa di mimo lasiko to  n ba awon akoroyin nilu Maiduguri.
Nwachukwu fikun-un pe, iko omo ogun ohun seku pa omo ogun olote kan, bee si nii  won gba enikan ti o wa ninu ihamo sile nibi ti won fi pamo si lagbegbe Afa lojo Aiku(Sunday).
O fikun un pe, iko omo ogun sawari ipago awon omo ogun olote ohun lasiko ise akanse Lafiya Dole naa.
“Awon omo ogun se ikolu si ipago omo ogun olote Boko Haram ti o wa lagbegbe Benisheikh, nipinle Borno.
Iko omo ogun sawari ipago naa lojo Aiku(Sunday), lagogo mesan an owuro.
O tenumo pe, awon omo ogun je ipago ohun run patapata lai ku enikan soso.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages