Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Tuesday, April 24, 2018

NIS mu asofin Melaye



Ile ise to n ri si oro irin ajo ni Naijiria The Nigerian Immigration Service (NIS) ti fowo sinkun mu asofin Dino Melaye ni papako ofurufu Nnamdi Azikiwe lojo Aje(Monday) nilu  Abuja.
Gege bi agbenusoro fun ile ise ohun, ogbeni Sunday James so pe, won mu asofin Melaye gege bi ase lati enu awon torokan gbangban.
Ile ise NIS, so oro ohun di mimo lori ero ayelujara won pe, awon ti fowo sikun mu asofin Melaye ti o je asoju-sofin eka ila oorun ipinle Kogi.
Ile-ise olopaa ti o sese fesun kan asofin Melaye pe, O lowo si kiko ohun ija oloro fun awon omo ogun olote.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages