Your campus No 1 Website

Business

test

Breaking

Post Top Ad

Your Ad Spot

Saturday, April 21, 2018

Epo robi bureke lorile ede Naijiria, owo ori epo robi di $73.79


owo epo robi bureke lorile ede Naijiria
Idagbasoke ti n de ba iye owo ti orile ede Naijria yoo ma ri lori epo robi. Lojo Eti yii ni ajo to n ri si bi won se n n ta epo robi lagbaaye iyen OPEC fenuko lori bi adinku yoo se de ba iwon epo robi ti awon orile ede kan, n ta epo robi si orile ede miiran.Eyi lo faa ti iye owo ori epo robi agba kan se lo soke si 73.79 dola.
Orile ede Amerika ta agba  epo robi tire ni 68.40 dola , amosa orile ede Naijiria ta agba epo robi tire naa  ni 74.75 ati  69.56 dola, ni eyi to je pe o tun gbe peli ju iye ti won ti n ta agba epo robi won lati osu kejila odun 2014  lo.
Ile ise  to n ri si tita ati rira epo robi ni ekun Texas(WTI)yoo tun se agbekale ere ti won yoo ri lori epo lose yii. Bi adinku se de ba iwon epo robi ti awon orile ede kan n ta si orile ede miiran tun je ki owo ori epo robi  tun goke si i.
Orile ede Saudi Arabia lo ta epo  robi julo laarin gbogbo awon orile ede to wa lagbaaye, amosa lati odun 2017 ni ajo OPEC ti n sa  ipa won lati ri i pe adinku ba iwon epo robi ti awon orile ede kan n ta a si orile ede miiran.

No comments:

Post a Comment

FcTables.com

Post Top Ad

Your Ad Spot

Pages