Leyin odun mejilelogun ti akonimoogba agba iko agbaboolu Arsenal, Arsene Wenger ti n tuko iko agbaboolu ohun, Wenger ti kede bayii lati fi iko naa sile lopin saa to n lo lowo yii.
Ninu oro re, O so pe, asiko ti to wa yii, lati tun tesiwaju pelu aye miran.
O fi kun un pe,“leyin gbogbo iforowero, ipade pelu awon toro kan gbangban ninu iko Arsenal, Mo lero pe asiko ti to lati fi iko yii sile gege bi akonimoogba ti saa to n lo lowo yii ba pari.
“Mo dupe lopolopo fun anfani lati sin iko yii fun opolopo odun.
“Mo tuko yii tokan-toka pelu oye kikun.
“Mo tuko yii tokan-toka pelu oye kikun.
“Mo fe dupe lowo awon osise, awon agbaboolu, oludari gbogbo, ati papajulo awon ololufe iko yii, fun atileyin ati ife won ti o legbe ti won fi han si mi lati igba ti mo ti n tuko iko yii.
“Mo ro awon ololufe wa lati tun bo duro sin-sin pelu iko yii lati pari si ibi ti o lapere lori tabili ni saa yii.
“Si awon ololufe wa , e ri daju lati se itoju awon ohun ini wa gbogbo.
“Ife mi ati atileyin mi fun iko yii, yoo wa ti ti ayeraye.”
“Mo ro awon ololufe wa lati tun bo duro sin-sin pelu iko yii lati pari si ibi ti o lapere lori tabili ni saa yii.
“Si awon ololufe wa , e ri daju lati se itoju awon ohun ini wa gbogbo.
“Ife mi ati atileyin mi fun iko yii, yoo wa ti ti ayeraye.”
Omo odun méjídínláàdọ́rin ohun, bere si ni n tuko agbaboolu Arsenal lati odun 1996, ti O si tuko ohun gba ife eye idije ile geesi meta (EPL), ife eye idije FA meje.
Arsene Wenger tuko agbaboolu Nancy, Monaco ati Nagoya Grampus.
Stan Kroenke , ti o je eni ti osuwon re po julo ninu awon toro kan gbangban ninu iko ohun, gboriyin bantabanta fun Wenger fun ise takuntakun re ti o ti n se lati eyin wa, bee si ni o fi da awon ololufe iko naa loju lati ropo re pelu akonimoogba miran ti o
No comments:
Post a Comment